Sulu Gambari L'oba wa o
Ishola Opo Lo'ba way
Imamu Fulani ni o si ki irun jimoh fun Baba wa

Won ni pe oroju ni ilorin oo
Oun tan ta ni owon gogo
Ishola Opo yen ko ni gba abosi laye loja oba
Sulu Gambari L'oba wa o
Ishola Opo Lo'ba way
Imamu Fulani ni o si ki irun jimoh fun Baba wa
Ma Koja to ba mu Ibori o
Ni waju ile oba wa
Ani Makoja to bà mu ibori oo
Ni waju ile oba wa
Ko si aye fun ko ni itiju, ko bori kotun boramo
Sulu Gambari L'oba wa o
Ishola Opo Lo'ba way
Imamu Fulani ni o si ki irun jimoh fun Baba wa
Ja ara mo ishe ko le di Oga oo
Ko si ifarawa ni ilorin
Kosi imele ko si Abosi, wo inu moto kosinmi Agbaja
Sulu Gambari L'oba wa o
Ishola Opo Lo'ba way
Imamu Fulani ni o si ki irun jimoh fun Baba wa
Imamu Fulani ni Asaju oo
Ti gbogbo ilu n berí fun
Ti won di ikuku ti won raa baaba se Sheu fun awon oba wa
Sulu Gambari L'oba wa o
Ishola Opo Lo'ba way
Imamu Fulani ni o si ki irun jimoh fun Baba wa
Imaamu Basheeru ti naro oo
Ti gbogbo ilorin duro Dede
Ani raka ni won o si ki ni eidi lojo ileya
Sulu Gambari L'oba wa o
Ishola Opo Lo'ba way
Imamu Fulani ni o si ki irun jimoh fun Baba wa
Won ni kaa kewu ka kawe o
Ka nishe ka ma ti owo na
Kafe iyawo kashanfani ki aye o yewa gbedemuke
Sulu Gambari L'oba wa o
Ishola Opo Lo'ba way
Imamu Fulani ni o si ki irun jimoh fun Baba wa
O fe da bi pe oti wa ile pe
Ofe da bi pé oti wa ile pe
Si ilu Alfa Alimi Janta
Kosi n to le wó ilorin
Ilu kan ti o si aye fun eegun
Esin ni won gun ni ilorin
Ko si ebo ni inu ilu wa
Baba ijebu o le wo ilorin
Ko si oun to tun le Jo tete
Da mo lekun Ashekondu
Tale Tawuro ni won kewu
Ko si igba ti e o le wo ilorin
Ko Ma pade awon kowope
Ilu ilorin ni won wa
Gbogbo awon tan si fe kewu
Ilu ilorin ni won wa
Won ni ilu to jina sina
Sunmo Alujannah peki peki
Sunmo Alujannah peki peki
Ke kalo si jimoh ilu wa
O pade oun ti o Jo e loju
Oba wa n to leyin imaamu
Quraani na o fi se idajo
Hadeethi na o fi soro won
Bi Ramadana wole de
Eko lotun olele losi
Won pin semo ati iresi
Imaamu ti n be ni ilorin
Ni olori awon imaamu
Ladaani ti n be ni ilorin
Ni n pe irun ni agbaye
O pade awon to lowo
To ni esin to n kirun Dede
Ofe ni won fe Iyawo Nbe
Alubarika na si fin wa
Won bere pe ibo ni iwo n gbe
A n sun ni Alujannah ni fàà
Sulu Gambari L'oba wa o
Ishola Opo Lo'ba way
Imamu Fulani ni o si ki irun jimoh fun Baba wa
أعوذ بالله من الشيطان الرجيم
بسم الله الرحمن الرحيم
وبه نستعين
الحمدلله ربّ العالمين
الرحمن الرحيم
ملك يوم الدين
إياك نعبد وإياك نستعين
إهدنا الصراط المستقيم
صراط الذين أنعمت عليهم
غير المغضوب عليهم ولا الضالين
Sulu Gambari L'oba wa o
Ishola Opo Lo'ba way
Imamu Fulani ni o si ki irun jimoh fun Baba wa
Sulu Gambari L'oba wa o
Ishola Opo Lo'ba way
Imamu Fulani ni o si ki irun jimoh fun Baba wa