L'odun Meje Lafi Dé bi taà si fe dé
L'odun Meje Lafi niun taà si fe ní
Pelu imo Omo Abdullahi
L'odun Meje Lafi Dé bi taà si fe dé
L'odun Meje Lafi niun taà si fe ní
Pelu imo Omo Abdullahi
Sheu Ādama lomoda
Olanan Loni titi
Odabí Ojo kan to Shude
Wan Shebi orotan Kià Kià
Gbogbo everybody lonkan Toto
Oro sagbádo loba gbo
Oro si ege tinfaka
Orosebe lobatun tà
Odunmanle pe Ādama
Yiti gbemande totun po
Odun Moke pé Ādama
Yi lojo toro wa ni sanmo
Osi lanfanin otudun
Niwoyi leyin gbe tira aa
Niwoyi leyin gbe tira
Latoru lawan tinkewu
Bodosan awa otunin sun
Ādamal Aloriy lobun
Mimo te o lé so boshenwa
Shekoni baje lai la
Wanle Lero pe mulhimun
Ni shishentele tiwan to
Eko ni wan peyi n Markazu
Obotopewan lokoman
Fun awan baba Ādama
Abdullahi Aloriy fe
Wan sopé Alao Ādama
Ni iwe eri ni azharu
Showadabi dandan gbojunbe
Odabi dandan gbojunbe
Osiman dumin fún guru
Tokawé kawé dé Jebba
Osilohun oni kewu man
Kewu tí awa fin Lowo
Kewu ti awa fin kole
Kewu ti awa fininyi
L'odun Meje Lafi Dé bi taà si fe dé
L'odun Meje Lafi niun taà si fe ní
Pelu imo Omo Abdullahi
L'odun Meje Lafi Dé bi taà si fe dé
L'odun Meje Lafi niun taà si fe ní
Pelu imo Omo Abdullahi
Ní Keté taà tí Shetàn nu Ogba lojosí
Tan wà fun wà ni Sha'adah eko wa
Tan tun fun wà lalubaarika Afa wà
Ta wa jade
Ta wa jade sinú Aye lashe Afa wa
Niwontin fe wa, koda won tun Man sorowa
Pé Lagegé
Pé Lagegé le o ti ri won tan yanju nkewu
Won tun fun wa laye katun Maa joko nwaju
Tebariwa aa
Tebariwa emasheje koma yayin lenu
L'odun Meje Lafi Dé bi taà si fe dé
L'odun Meje Lafi niun taà si fe ní
Pelu imo Omo Abdullahi
L'odun Meje Lafi Dé bi taà si fe dé
L'odun Meje Lafi niun taà si fe ní
Pelu imo Omo Abdullahi
Won ni kà so ohún to tun le bawa leru
Shey kewu ni kolési kiímasoro enu
Won fe ni ka kewu lawujo awon oloba
Won fe ni kaa kewu lawujo awon oloye
Won fe fun wa laye nijoko ijoba
Oshey je awa
Oshey je awa na o pe ti aroye imo bade
Won fe gbowa nibi tan tin soro olohun
Kilowa shey to fi je omo sheikhu Ādama
Baba to fí mímo ko ila kuro fun eleko
Baba to fí mímo ko ila kuro fun eleko
Won tun bimo to yan to tun fi iwa jowon gan
Adebayo Alatanda Baba Babatunde
Natin gbeki
Niwontun gbekiri Oro ti Mudeeru yi baso
Kato wi kaa to fo won tun ti sokan jade
Shey Lagegé won o lé dake nibi oro mimo
To ba je ti sunna teyin fi okun fun lorun
Baba Lagegé
Bà'lagegé yi o situn mia damun yi nhi
Kolohun dakun ma Pawon Kisiki yi fun wa
Tori imo
Wo Ola imo Omo Abdullahi
L'odun Meje Lafi Dé bi taà si fe dé
L'odun Meje Lafi niun taà si fe ní
Pelu imo Omo Abdullahi
Ka kewu ko lo Markaziyu lo le shey bayen
O fe jade yi o ti taniyan re shey koda
Oro Olohun ati esin ni o tun maa jafun lode
Banshee kowa nini Markazi niyen ka shey
Babà to bi wa sheikhu Ādama oni mimo
Lo'moda ni won ti barika Afa wa
Kosi n tole fi igi gun Oju sheikhu Ādama
Aponlé lo shey fun awon to saaju re ni mimo
O tun fe won fe awon ti o tun maa je arole won
O'daruko won sibi ti aye otile maariwon
Won ni iro ni sheikhu Ādama ko lé to awon
Lolohun bawo oun to shey loju won ati leyin
Loba gbewon
Lobagbewon soke ti giga re kolopin
Loba tun shey Dawla won komawa kanrin kese
Loba tun fi barka si mimo omo Ādama
Ki Olohun bawa
Ki Olohun bawa ke Omo Abdullahi
L'odun Meje Lafi Dé bi taà si fe dé
L'odun Meje Lafi niun taà si fe ní
Pelu imo Omo Abdullah
غفران ربّي وسلامه
عليك آدم عبد الله
دعني أجيب من يسألني
عن الإلورى عبد الله
فهو الذي قد أشرقت
أنواره في أرض الله
قد جاهد الشّيخ دون افترا
حقّ الجهاد لدين الله
حتّى بنى لله بيتاً
يا حبّذا ببيت الله
ومركز التّعليم معْ
منبع العلوم عطاء الله
أفديك روحي
أفديك روحي
أفديك روحي يا مركزالت
تعليم حقّا حصن الله
غفران ربي وسلامه
عليك آدم عبد الله
L'odun Meje Lafi Dé bi taà si fe dé
L'odun Meje Lafi niun taà si fe ní
Pelu imo Omo Abdullahi
قد ساد قوماً بالعرفان
يرقى صعودا بعلم الله
ساد رجالا قاد هداة
بشراك آدم عبد الله
فهو الفريد في عصرنا
أعجوبة الكون نور الله
هو واعظ ومؤلف
ومدرّس من أجل الله
أيّد إلهي مديرنا
أيّد إلهي مديرنا
شبل الإلورى حبيب الله
صلاة ربي وسلامه
على محمد عبد الله
غفران ربي
غفران ربي وسلامه
عليك آدم عبد الله
عليك آدم عبد الله
آدم عبد للباقي
عبد الله الألورى
آدم عبد للباقي
عبد الله الألورى
آدم عبد للباقي
عبد الله الألورى
آدم عبد للباقي
عبد الله الألورى
Eba n kibosi Baba Rahmah
عبد الله الألورى
Agbogun Mati Omo omoda
عبد الله الألورى
Kul huwallahu fun sheikhu
عبد الله الألورى
Eni to so nahwu di eko elewe
عبد الله الألورى
Baba Adebayo Omo Omo'da
عبد الله الألورى
Ki nan pe oruko Afa yin na
عبد الله الألورى
Baba Adebayo Omo omo'da
عبد الله الألورى
To so nahwu di eko elewe
عبد الله الألورى
Markaziyul Haqeeqiy
عبد الله الألورى
Ki lo so fun yin nilekewu
عبد الله الألورى
Igfir Abal Habeebiy
عبد الله الألورى
O tun gbe Sha'adah lewa lowo
عبد الله الألورى
O ti gbe Sha'adah lewa lowo
عبد الله الألورى
O somo tutu to go to n jato
عبد الله الألورى
O ti gbe Sha'adah lewa lowo
عبد الله الألورى
O somo gungo gun obe ni Mushin
عبد الله الألورى
Nibo le gbe Sha'adah yen si na
عبد الله الألورى
Di sheikhu tin joko n waju
عبد الله الألورى
O so olori awon omo wobe
عبد الله الألورى
Di Ustaazu ti koje o ramaye
عبد الله الألورى
O ja pan pa lorun awon Rafa
عبد الله الألورى
Osowon dogo gbogbo aye para
عبد الله الألورى
Markaziy ni Daddy mi modupe
عبد الله الألورى
Morkaziy ni Daddy mi modupe
عبد الله الألورى
Morkaziy ni mummy mi modupe
عبد الله الألورى
Morkaziy ni baby mi Shotan
عبد الله الألورى
Awon ota mi o ku kewu
عبد الله الألورى
Awon ota wa oni ri owo
عبد الله الألورى
Nibo legbe Sha'adah yen si na
عبد الله الألورى
Showa ni eko abi Ilorin
عبد الله الألورى
Abdullahi L Aloriy
L'odun Meje Lafi Dé bi taà si fe dé
L'odun Meje Lafi niun taà si fe ní
Pelu imo Omo Abdullahi
L'odun Meje Lafi Dé bi taà si fe dé
L'odun Meje Lafi niun taà si fe ní
Pelu imo Omo Abdullahi