Back to Top

Evang. Elias Ajibise - BÙKÉÈ NEW Lyrics

Evang. Elias Ajibise - BÙKÉÈ NEW Lyrics

Chorus: Búké bùké búké Eko mi
Kò s'èyìn yangan Ògá Ògo
Búké bùkè búké àkàrà mi Kò s'èyìn erèé Olódùmarè
Mo m'ope at'iyin wá F'Oba Ògo o

Baba mi at'Olorun mi Mo dupe o
Ola at'ogo ma ni f'oruko Re
Nibi to ba'ye mi de o o thank You Sir
Ogo ola ati iyin ni f'oruko Re.
Mo r'onu jinnle ohun to SE laye MI o iyen lo mu ki nyaa tètè m'ope wa Ohun gbogbo to fi fun mi o Ìwo ni ngo fi sin
Ogo ola ati iyin ni f'oruko Re

Búké bùké búké Eko mi Kò s'èyìn yangan Ògá Ògo
Búké bùkè búké àkàrà mi kò s'èyìn erèé Olódùmarè Mo m'ope at'iyin wá f'Oba Ògo o

Igba to dabi pe ko s'ona mo rara mo ke pe Jesu o la'na fun mi l'aginju nigba to dabi pe ko sí ireti mo o mo ke pe Jesu O la'na abayo fun mi igba to dabi pe ogun ti bori mi mo ke pe Jesu O mu mi bori ogun
Kinni maa je yo oti maa fi gbàgbé Re o
Everything wey You give me I go take give bùkéè to You
Kinni maa je yo o ti maa fi gbagbe Re o
Everything wey You give me I go take give bùkéè to You;

Maa f'ijo mi bùkéè
Bùkéè bùkéè
Ma f'orin mi bùkéè
Bùkéè bùkéè
Ma f'atewo mi bùkéè ee
Bùkéè bùkéè
Ma f'aye mi bùkéè ee
Bùkéè bùkéè
Ohun gbogbo to o fun mi
Bùkéè bùkéè
Ma fi bùkéè fun Baba
Bùkéè bùkéè
Ma fi bùkéè f'Olorun orun.
Bùkéè bùkéè
Ma f'aye mi bùkéè ee
Bùkéè bùkéè!

Ile ti o ko agbara re ko Mase fi ni ayalegbe re lara o
Owó ti o ni agbara re ko Ma f'iya j'eni ti o ni o beru Olorun
Ipo oga to wa yen agbara re ko
Ma fi ni àwon to nsise labe re lara o
Èyìn oloselu ta dino yan sipo
E ma j'ayekaye ee e se rere
Let the poor breath tori atubotan o
Oore ofe le ni oo se b'Olorun ni
Agbara re ko aanu lo ri gba
Mimoose re ko o se b'Olorun ni
Agbara re ko aanu lo ri gba
Mimoose re ko o se b'Olorun ni
Ma f'aye mi bùkéè joor!
Bùkéè bùkéè
Fi bùkéè s'Oba to da mi
Bùkéè bùkéè
Everything wey I be
Bùkéè bùkéè
I go take it bùkéè to Jesus
Bùkéè bùkéè
Oo de fi ile yen bùkéè
Bùkéè bùkéè
Fi ipo to wa yen bùkéè ee
Bùkéè bùkéè
F'aye e bùkéè
Bùkéè bùkéè
Fi bùkéè s'Oba to da e
Bùkéè bùkéè
Oo de f'owo yen bùkéè ee
Bùkéè bùkéè
Fi bùkéè s'Olorun orun
Bùkéè bùkéè
F'ogbon at'iyin yen bùkéè oo
Bùkéè bùkéè
Ma fi yahoo
Bùkéè bùkéè
F'ewà to ni yen bùkéè
Bùkéè bùkéè
Má fi s'olóshó
Bùkéè bùkéè
Everything wey You give me Papa
Bùkéè bùkéè
I go take am bùkéè to You oooooo
Bùkéè bùkéè.
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.

English

Writer: Elias Ajibise
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid

Evang. Elias Ajibise - BÙKÉÈ NEW Video
(Show video at the top of the page)

Performed By: Evang. Elias Ajibise
Language: English
Length: 5:26
Written by: Elias Ajibise
[Correct Info]
Tags:
No tags yet