Mo gbeke mi le o
Olorun ti kii jani kule
Oba to npa majemu mo o
Olorun ti kii jani kule
Mo gbeke mi le o
Olorun ti kii jani kule
Oba to npa majemu mo o
Olorun ti kii jani kule
Apata ayeraye o
Se ibi isadi mii
Jeki omi ohun eje re
Se iwosan f'ese mi
Kil'o le w'ese mi nu
Ko si lehin eje Jesu
Ki l'otun le wo mi san
Ko si lehin eje Jesu
Nigbati okan mi ba sako lo
Kuro lodo re o baba mimo
Fi aanu fami pada sile
Jeki n r'aanu gba
Apata ayeraye o
Se ibi isadi mii
Jeki omi ohun eje re
Se iwosan f'ese mi
Etutu f'ese ko si
Ko si lehin eje Jesu
Ise rere kan ko si
Ko si lehin eje Jesu
Mo gbeke mi le o
Olorun ti kii jani kule
Oba to npa majemu mo o
Olorun ti kii jani kule
Apata ayeraye o
Se ibi isadi mii
Jeki omi ohun eje re
Se iwosan f'ese mi
Gbogbo igbekele mi
Ireti mi l'eje Jesu
Gbogbo ododo mi ni
Eje kiki eje Jesu
Oh victory in Jesus
My Saviour for ever
He sought me and bought me
With His redeeming blood
Apata ayeraye o
Se ibi isadi mii
Jeki omi ohun eje re
Se iwosan f'ese mi
Ohun ti mo fi nsegun
Eje kiki eje Jesus
Ngo de'le mi nikehin
Nipa riro mo eje re
Mo gbeke mi le o
Olorun ti kii jani kule
Oba to npa majemu mo o
Olorun ti kii jani kule
Apata ayeraye o
Se ibi isadi mii
Jeki omi ohun eje re
Se iwosan f'ese mi