E jii gbogbo okan to sunlo
E jii oo ipe ma fere dun
E jii gbogbo okan to sunlo
E jii oo ipe ma fere dun
Eji eji gbogbo okan to sun lo
Faramo emi a faramo Jesu faramo
Ipadabo Jesu ti de tan
Faramo emi a faramo Jesu faramo
Olugbala gbogbo araye
Faramo emi a faramo Jesu faramo
Opo onigbagbo lo ti sun loju ogun
Faramo emi a faramo Jesu faramo
Opolopo lo ntorogbe
Faramo emi a faramo Jesu faramo
Ejii ejii o
Ejii ejii o
Iwo apeyinda olorun fe o
Faramo emi a faramo Jesu faramo
Mase jeki isoro aye bori re
Faramo emi a faramo Jesu faramo
Asan laye o faramo oluwa
Faramo emi a faramo Jesu faramo
Backsliders e pada wale
Faramo emi a faramo Jesu faramo
Pansaga agbere e pada sile
Faramo emi a faramo Jesu faramo
Anu oluwa nduro de o
Faramo emi a faramo Jesu faramo
O ti se'leri yoo mu se
Faramo emi a faramo Jesu faramo
Jeremiah keta ese kejilelogun
Faramo emi a faramo Jesu faramo
Oni emi yoo wo ipehinda yin sano
Faramo emi a faramo Jesu faramo
Mase jeki ipehinda di titi lai
Faramo emi a faramo Jesu faramo
Ju etan sile room otito
Faramo emi a faramo Jesu faramo
Faramo Faramo Faramo Faramo Faramo Faramo Faramo
Faramo Faramo Faramo Faramo Faramo Faramo Faramo
Aye nlo sopin o
Aye nlo sopin
Aye nlo sopin o
Aye nlo sopin
Onigbgbo e ma jafara o
Aye nlo sopin
Onigbgbo e ma jafara o
Aye nlo sopin
Opin ti de tan
Aye nlo sopin
O ti de tan
Aye nlo sopin
Onigbgbo e ma jafara o
Aye nlo sopin