Gbigbega loluwa/3x
Mo gbe ọga
GBigbega Loluwa /3x
Mogbe ọ ga
Igbati moro ore ti Jesu
Se layemi o/2x
Mo fo soke mo kalleluyah
Mo yin baba logo
Nigbati moro ore ti Jesu se laye mi oo
Mobere mole mo ke Alleluyah mo yin Baba logo
Nigbati moro ore ti Jesu se laye mioo
Mofopefun ... ọpọooo ọpo
Iwọ Lolorun Isreali
Ari pase rẹ lori okun
Ogun iji lẹsin
Mo gbeo ga
Iwọ Lolorun Hannah
Olorun Eliṣabeti
Ọba to sọ agan di Ọlọmọ oo
Mo gbe o ga