Back to Top

Mairo Ese - Omo Eniyan [Album] Lyrics

Mairo Ese - Omo Eniyan [Album] Lyrics
Official

Omo eniyan
Onigbagbo

Jesu yi ma de tan
Lati se dajo awa eda
Ko mani gbebi fun alare
O ba ye se owo re wo o
O le gbin igbado ko kala
O ma le se buburu gbare
Idajo Olurun ma de tan
Oremi ranti ati sun re

Omo eniyan
Omo eniyan eh eh ye se owo re wo o
Eniyan eniyan eniyan se ranti ati sun re
Onigbagbo onigbagbo ye se owo re wo o
Eniyan eniyan se ranti ati sun re

Ounto'ju re o ma ri
Ati eyi te ti re ko gbo oooo
Opa gbogbo re po ofin ba ara ijo je kiri aa
O gbo tile ogbo tode
O de wa keyin oloro si rawon
So se bo Oluorun o ri e ni
O ba se ranti ati sun re

Omo eniyan
Omo eniyan ye se owo re wo o ye se owo re wo o
Eniyan eniyan se ranti ati sun re
Onigbagbo onigbagbo ani ko ye se owo re wo o ohohoh
Eniyan eniyan se ranti ati sun re

Oooooh oh oh oh oh ooooo

Ofaye re fun Jesu tan
Otun wa gbaye re pada
Onigbagbo la mo o si
Oma de se wa doni gbagbe
Se tipe ba dun nje o rope ole ba baba mi lo
Eniyan eniyan se ranti ati sun re

Omo eniyan
Omo eniyan ye se owo re wo o ye se owo re wo o
Eniyan eniyan eniyan se ranti ati sun re ranti eleda re oo
Onigbagbo onigbagbo ye se owo re wo o ye se owo re wo o
Eniyan eniyan se ranti ati sun re

Eniyan eniyan eniyan oooo se ranti ati sun re
Oluorun nri ee ooo ranti se ranti ati sun re
Ma a faye e ba aiye ra e je ooo
Omo eniyan se ranti ati sun re hahaha
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.

Writer: Oghenemairo Okechukwu Ese
Copyright: Lyrics © EVENT MANAGEMENT INTERNATIONAL LTD

Back to: Mairo Ese

Mairo Ese - Omo Eniyan [Album] Video
(Show video at the top of the page)

Performed By: Mairo Ese
Length: 5:18
Written by: Oghenemairo Okechukwu Ese
[Correct Info]
Tags:
No tags yet