Jeka- jose oo oya, oro atunse loku oya
Jekajose oo oya, atunse loku kajose
Eyin alase ijoba oya, ijoba apapo oya
Ijoba ipinle oya, at'ijoba ibile oya kajose oya
Gbogbo oga ile-ise oya, ateyin osise oya
Eyin oludamorann oya, ateyin alakoso kajose
Asofin at'asoju oya, ati gbogbo agbofinro oya
Eyin adajo oya, at'agbejoro gbogbo oya
Gbogbo onisowo kajose, at'onise-adani oya
Eyin eleto aabo oya, ateyin oluko oya
Gbogbo akeko-giga oya, ateyin ojewewe kajose
Gbogbo oniwe-iroyin oya, ateyin sorosoro oya
Eyin agbasese oya, gbogbo onise-owo oya
Eyin onise-iwosan kajose, isegun-ibile gbogbo oya
Gbogbo olorin pata oya, ateyin osere ori itage oya
Gbogbo loba loba oya, at'ijoye gbogbo kajose
Gbogbo loba loba oya, at'ijoye gbogbo oya
Micho Ade nkilo oya, tori ojo ola oya
Micho Ade nkilo kajose, tori ojo ola
Oya, kajose
E jeka jose
E je ka jose ni o,
E je ka jose kole toro
Eyin ojise olorun tooto
E jeka jose ni o
Ibi e baa ti kuro lori majemu atilana
E je'a jose kole toro
E lo satunse
E je ka jose ni o
Eyin musulumi ododo
E je'a jose kole toro
Ibi e baa ti gbowo ga j'oro olorun lo
E je ka jose ni o
Atunse dowo yin
E je'a jose kole toro
Baale ile ati iyawo ile
E je ka jose ni o
Eyin obi loro yi kan julo
E je'a jose kole toro
Ti gbogbo wa baa tile se
E je ka jose ni o
Abuse-buse
E je'a jose kole toro
Kajo sasaro
E je ka jose ni o
Asaro kale tesiwaju
E je'a jose kole toro
E je ka jose
E jeka jose ni o
Ara mi o e je ajo tunleyi se ooooo