Back to Top

Abo Mi Video (MV)

Performed By: Mo Bolaji
Language: English
Length: 5:24
Written by: Anthonia Afuape

Mo Bolaji - Abo Mi Lyrics
Official

Abo mi, Asoro d'ayo
Abo mi, Alewilese
Abo mi, Asoro d'ayo
Abo mi, Alewilese
Baba mi o, aiye mi d'owo re
Baba mi o, mo fi le o l'owo
Baba mi o, aiye mi d'owo re
Baba mi o, tun le aiye mi se
Eledumare (Ee ee), Baba mi o (Baba mi o)
Atobiju (Atobiju), Olorun oluda aiye (Ooo oo)
Eledumare (Eledumare), Baba mi o
Atobiju (Atobiju), Olorun oluda aiye
(Aaa aaa)
Ogo, iyin lo ye o Baba
Ope fun Eledumare
Fun Oba to da wa si o
Iyin lo ye o, Awamaridi Oba awon Oba
Hosanna l'ohun orun ke
Fun Oba Edumare Oba toto ye eee
(So wipe ogo) Ogo
(iyin lo ye o Baba) iyin lo ye o Baba
(Ope fun Eledua) Ope fun Eledumare
(Fun Oba to da wa si o oo) Fun Oba to da wa si o
(Iyin lo ye ooo) Iyin lo ye o
(Awamaridi Oba awon Oba) Awamaridi Oba awon Oba
(Hosanna lohun orun ke) Hosanna lohun orun nke
(Fun Oba Edumare Oba toto) Fun Oba Edumare Oba toto
Abo mi, Asoro d'ayo
Abo mi, Alewilese
Abo mi, Asoro d'ayo
Abo mi, Alewilese
Baba mi o, aiye mi d'owo re
Baba mi o, mo fi le o l'owo
Baba mi o, aiye mi d'owo re
Baba mi o, tun le aiye mi se
(Eledumare!)
Eledumare (Eledumare ee), Baba mi o (Atobiju Olorun aseda orun)
Atobiju (Olorun oo), Olorun oluda aiye
(You are my healer) Eledumare, (I worship you for the rest of my life) Baba mi o
(Glorious God, wonderful God, my creator, my deliverer) Atobiju, Olorun oluda aiye (Olorun)
(OO oo ooooo)
Eledumare, Baba mi o (Erujeje leti okun pupa)
Atobiju (A yin o logo, a gbe o ga), Olorun oluda aiye
(Eledumare) Eledumare, Baba mi o (Oo oooo)
Atobiju (Atobiju), Olorun oluda aiye (Olorun oluda aiye eee)
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.

English

Abo mi, Asoro d'ayo
Abo mi, Alewilese
Abo mi, Asoro d'ayo
Abo mi, Alewilese
Baba mi o, aiye mi d'owo re
Baba mi o, mo fi le o l'owo
Baba mi o, aiye mi d'owo re
Baba mi o, tun le aiye mi se
Eledumare (Ee ee), Baba mi o (Baba mi o)
Atobiju (Atobiju), Olorun oluda aiye (Ooo oo)
Eledumare (Eledumare), Baba mi o
Atobiju (Atobiju), Olorun oluda aiye
(Aaa aaa)
Ogo, iyin lo ye o Baba
Ope fun Eledumare
Fun Oba to da wa si o
Iyin lo ye o, Awamaridi Oba awon Oba
Hosanna l'ohun orun ke
Fun Oba Edumare Oba toto ye eee
(So wipe ogo) Ogo
(iyin lo ye o Baba) iyin lo ye o Baba
(Ope fun Eledua) Ope fun Eledumare
(Fun Oba to da wa si o oo) Fun Oba to da wa si o
(Iyin lo ye ooo) Iyin lo ye o
(Awamaridi Oba awon Oba) Awamaridi Oba awon Oba
(Hosanna lohun orun ke) Hosanna lohun orun nke
(Fun Oba Edumare Oba toto) Fun Oba Edumare Oba toto
Abo mi, Asoro d'ayo
Abo mi, Alewilese
Abo mi, Asoro d'ayo
Abo mi, Alewilese
Baba mi o, aiye mi d'owo re
Baba mi o, mo fi le o l'owo
Baba mi o, aiye mi d'owo re
Baba mi o, tun le aiye mi se
(Eledumare!)
Eledumare (Eledumare ee), Baba mi o (Atobiju Olorun aseda orun)
Atobiju (Olorun oo), Olorun oluda aiye
(You are my healer) Eledumare, (I worship you for the rest of my life) Baba mi o
(Glorious God, wonderful God, my creator, my deliverer) Atobiju, Olorun oluda aiye (Olorun)
(OO oo ooooo)
Eledumare, Baba mi o (Erujeje leti okun pupa)
Atobiju (A yin o logo, a gbe o ga), Olorun oluda aiye
(Eledumare) Eledumare, Baba mi o (Oo oooo)
Atobiju (Atobiju), Olorun oluda aiye (Olorun oluda aiye eee)
[ Correct these Lyrics ]
Writer: Anthonia Afuape
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid

Back to: Mo Bolaji

Tags:
No tags yet