Back to Top

Olorun Mi Video (MV)




Performed By: Mo Bolaji
Language: English
Length: 7:16
Written by: Anthonia Afuape




Mo Bolaji - Olorun Mi Lyrics
Official




Hm mm Baba mi Eledumare
Hmm mmm
Iwo ni Olorun mi
Mo juba re
(Iwo nii) Iwo ni Olorun mi
(Kabiyesi re) Kabiyesi
(Iwo l'Oba) Iwo ni Olorun mi
(Mo ma juba re) Mo juba re
(Iwo ni, iwo ni) Iwo ni Olorun mi
(Kabiyesi re) Kabiyesi (Hmmmm)
Mo yin o aaa
Ologo ju lo, oloruko nla
Sin sin le mi o ma sin o titi aiye mi o
(Iwo ni) Iwo ni Olorun mi
(Mo ma juba re) Mo juba re
(Iwo ni oba, iwo ni oba) Iwo ni Olorun mi
(Kabiyesi o) Kabiyesi
Bi iya ati baba ba ko mi sile
Oluwa yio tewo gba mi
When my father and my mother forsake me
The lord will receive me
(Iwo l'Oba) Iwo ni Olorun mi
(Mo juba re) Mo juba re
(Alagbada ina, alawotele orun) Iwo ni olorun mi
(Iwo ni kan so so, kan sho oo) Kabiyesi
(Oba tin f'oba je iwo l'Oba) Iwo ni olorun mi
(Olorun mi, Eledumare) Mo juba re
(Mo juba re) Iwo ni Olorun mi
(Iwo ni Olorun mi) Kabiyesi
Mo gbe ke le iwo nikan o Oluwa mi
Iwo ni Olorun mi
N'je ti re titi lai ati lai lai
Olufe okan mi
(Olorun mi eee) Iwo ni Olorun mi
(You are my God forevermore) Mo juba re
(And I will worship you for the rest of my life) Iwo ni Olorun mi
(Iwo lo'lorun mi ooo, Kabiomasi) Kabiyesi
Ranti ojo yen to gba nkan to bere
Ranti bi Olorun se pese fun o
Ranti bi Olorun se gba o la lowo aiye
Ranti b'o se s'ope lojo yen
Ranti b'o se jo
Ranti idunu ayo re
Ma gbagbe o
Because when things get tough, you are still expected to praise him the same -
B'orun ba n'ran, t'iji ba nja, o si ye ko yin Oluwa l'ogo
Yin, ko si gbe oruko re ga
Ohun ni oba ton se ohun gbogbo ni akoko tio to
Aseyi owu ni orun ati ni aiye
Ni okun ati ni ogbun gbobo
Alakoso gbogbo emi eniyan
Ibere ati opin
(Kabiomasi o)
(Iwo ni Olorun mi) Iwo ni Olorun mi
(Olugbala Olorun olutoju aiye wa) Mo juba re
(Adani ma gba gbe eni, owi be se be) Iwo ni Olorun mi
(Olorun asoromaye) Kabiyesi
(Kabiomasi ooo)
Iwo ni Olorun mi
Mo juba re
Iwo ni Olorun mi
Kabiyesi
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


English

Hm mm Baba mi Eledumare
Hmm mmm
Iwo ni Olorun mi
Mo juba re
(Iwo nii) Iwo ni Olorun mi
(Kabiyesi re) Kabiyesi
(Iwo l'Oba) Iwo ni Olorun mi
(Mo ma juba re) Mo juba re
(Iwo ni, iwo ni) Iwo ni Olorun mi
(Kabiyesi re) Kabiyesi (Hmmmm)
Mo yin o aaa
Ologo ju lo, oloruko nla
Sin sin le mi o ma sin o titi aiye mi o
(Iwo ni) Iwo ni Olorun mi
(Mo ma juba re) Mo juba re
(Iwo ni oba, iwo ni oba) Iwo ni Olorun mi
(Kabiyesi o) Kabiyesi
Bi iya ati baba ba ko mi sile
Oluwa yio tewo gba mi
When my father and my mother forsake me
The lord will receive me
(Iwo l'Oba) Iwo ni Olorun mi
(Mo juba re) Mo juba re
(Alagbada ina, alawotele orun) Iwo ni olorun mi
(Iwo ni kan so so, kan sho oo) Kabiyesi
(Oba tin f'oba je iwo l'Oba) Iwo ni olorun mi
(Olorun mi, Eledumare) Mo juba re
(Mo juba re) Iwo ni Olorun mi
(Iwo ni Olorun mi) Kabiyesi
Mo gbe ke le iwo nikan o Oluwa mi
Iwo ni Olorun mi
N'je ti re titi lai ati lai lai
Olufe okan mi
(Olorun mi eee) Iwo ni Olorun mi
(You are my God forevermore) Mo juba re
(And I will worship you for the rest of my life) Iwo ni Olorun mi
(Iwo lo'lorun mi ooo, Kabiomasi) Kabiyesi
Ranti ojo yen to gba nkan to bere
Ranti bi Olorun se pese fun o
Ranti bi Olorun se gba o la lowo aiye
Ranti b'o se s'ope lojo yen
Ranti b'o se jo
Ranti idunu ayo re
Ma gbagbe o
Because when things get tough, you are still expected to praise him the same -
B'orun ba n'ran, t'iji ba nja, o si ye ko yin Oluwa l'ogo
Yin, ko si gbe oruko re ga
Ohun ni oba ton se ohun gbogbo ni akoko tio to
Aseyi owu ni orun ati ni aiye
Ni okun ati ni ogbun gbobo
Alakoso gbogbo emi eniyan
Ibere ati opin
(Kabiomasi o)
(Iwo ni Olorun mi) Iwo ni Olorun mi
(Olugbala Olorun olutoju aiye wa) Mo juba re
(Adani ma gba gbe eni, owi be se be) Iwo ni Olorun mi
(Olorun asoromaye) Kabiyesi
(Kabiomasi ooo)
Iwo ni Olorun mi
Mo juba re
Iwo ni Olorun mi
Kabiyesi
[ Correct these Lyrics ]
Writer: Anthonia Afuape
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid

Back to: Mo Bolaji

Tags:
No tags yet