Back to Top

Mo Bolaji - Oruko Jesu (feat. Tope Alabi) Lyrics

Official

K'aiye to ta oruko Jesu, on dara fun wa
K'aiye to dale oruko Jesu, on dara fun wa
Eda yara pada sodo Jesu, ko dara fun o
K'aiye to ta oruko Jesu, on dara fun wa
K'aiye to dale oruko Jes, on dara fun wa
Eda yara pada sodo Jesu, ko le dara fun o

Omo gbo ohun Oluwa re ke tan tan si o oo, omo gbo

Ko ma si, eni to le gba o ninu iji aiye , ko ma si

Eni to gba wa la lowo iku oro, bee ni
O ja wa gba lowo egun ta bi wa si, bee ni
Owo to mo wa ko ni s'alai le gba wa, ra ra o
Eni to da eti koni s'alai gboron, bee ni

Aiye sare leje leje
Eniyan bu rin o f'ese ko ku
Awon ta mu latori aatan ta wa fi j'oba
Isoro de won sare eru won ti gba gbe eni to gba wa o
Ko ni s'alai gbawa tan won sare iku
Eda ro ju tan, on wa airoju o to ju su ni o, ee see
Eni to ni ala olumuse ala oruko re ni ala nla
Ese je je isoro de b'olorun soro mata Jesu, ofe la fun o
Odale pada ko ma ba bale lo
Oluta ofe igbala da owo won pada fun won
Ranti judasi ta ofe o pada pokun so
Eda yara pada sodo Oluwa re ko le dara fun o

[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.

English

Writer: Anthonia Afuape, Tope Alabi
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid

Back to: Mo Bolaji

Mo Bolaji - Oruko Jesu (feat. Tope Alabi) Video
(Show video at the top of the page)

Performed By: Mo Bolaji
Language: English
Length: 5:57
Written by: Anthonia Afuape, Tope Alabi

Tags:
No tags yet