Iwo Nikan Iwo Nikan Iwo Nikan ni Baba
Iwo Nikan Iwo Nikan ni Baba
Laye! Ko ma soba miran leyin Oluwa Laye!
Laye! Ko ma senikan ta le fi o we... Laye!
Laye! Iwonikan de lawimayehun Laye!
Baba lo le se Baba nikan lo le se o
Kijomole yin baba olorun loke ni Baba
Kijomole yin baba sebi Jehovah ni Baba...
Laye! Ko ma soba miran leyin Oluwa Laye!
Laye! Ko ma senikan ta le fi o we... Laye!
Laye! Iwonikan de lawimayehun Laye!
Ota lemilemi won o le bami
Sebi Iwo lo ko mi yo ni gbekun ota
Awimayehun Arugbo Ojo
Kabi o ko si Eleru Niyi
Laye! Ko ma soba miran leyin Oluwa Laye!
Laye! Ko ma senikan ta le fi o we... Laye!
Laye! Iwonikan de lawimayehun Laye!
Laye... Laye