Oshe o jesu O seun o
Oshe o jesu mo yin o
Titi a ye ni o ma gboruko re ga
Oshe o olorun ayo mo yin o logo jesu o Oseun o
Oshe o jesu O seun o
Oshe o jesu mo yin o
Titi a ye ni o ma gboruko re ga
Oshe o olorun ayo mo yin o logo jesu o oshe o
Oshe o jesu O seun o
Mo yin o logo jesu ataye ro
Titi a ye ni o ma gboruko re ga
Oshe o olorun ayo mo yin o logo baba oshe o
Oshe o jesu O seun o
Oshe o jesu mo yin o
Titi a ye ni o ma gboruko re ga
Oshe o olorun ayo mo yin o logo jesu o oshe o
Owo agbara to fi bami se temi
Tito bi re to fi dahun soro mi
Osehun jesu olorun mi mo yin o
Ose o agburo igba ni
Oshe o jesu O seun o
Oshe o jesu mo yin o
Titi a ye ni o ma gboruko re ga
Oshe o olorun ayo mo yin o logo jesu o oshe o
Owo agbara to fi bami se temi
Tito bi re to fi dahun soro mi
Mo yin o jesu olorun mi mo yin o
Ose o agburo igba ni
Oshe o jesu O seun o
Oshe o jesu mo yin o
Titi a ye ni o ma gboruko re ga
Oshe o olorun ayo mo yin o logo jesu o oshe o
Oluwa iwo ni pimi leyin re nko leni kan
La gbarra ni okun iwo lonimi ni fe ti gbaboiwo ba o lo
La kun nimi la fola oluwa iwo lonimi
Oluwa iwo ni pimi leyin re nko le niko
Lagbara ni okun iwo loni mini fe ti gbaboiwo ba o lo
La kun nimi la fola oluwa iwo lonimi
Mo ro pe ise titan
Oni sise Ku
Bara ni mo foro lo Ogberu mi lori o
Baba ti mo fe jo sun
Oba fe gbe ja mi ja
Bawo lo se fe se mi lore pataki to tun ju eyi lo o
Mo ro pe ise titan
Oni sise Ku
Bara ni mo foro lo Ogberu mi lori o
Baba ti mo fe jo sun
Oba fe gbe ja mi ja
Bawo lo se fe se mi lore pataki to tun ju eyi lo o
Oluwa iwo ni pimi leyin re nko le niko
Lagbara ni okun iwo loni mini fe ti gbaboiwo ba o lo
La kun nimi la fola oluwa iwo lonimi
Emi lo dalola mo wa yin o o
Emi lo gbe bori mo gbe o ga o
Ife re simi ga ju orun ihun aye
Ife re simi ga ju awon oke lo
Mio yin o Olorun ayo
Ife re simi ga ah o fe mi
Emi lo dalola mo wa yin o o
Emi lo gbe bori mo gbe o ga o
Ife re simi ga ju orun ihun aye
Ife re simi ga ju awon oke lo
Mio yin o Olorun ayo
Ife re simi ga ah o fe mi
Ore to louwa se lo mumi dupe
Ore to louwa se Lo mumi korin
O ra mi pada lowo aye
Eba mi yo
Mo bu sayo
Olorun mi sehun fun mi lojoju mo
Eba mi yo
Mo bu sayo
Olorun mi sehun fun mi lojoju mo
Emi lo dalola mo wa yin o o
Emi lo gbe bori mo gbe o ga o
Ife re simi ga ju orun ihun aye
Ife re simi ga ju awon oke lo
Mio yin o Olorun ayo
Ife re simi ga ah o fe mi
Ope Lori omo
Ope Lori oko
Ati Ope Lori aya
Jesu Melo ni mo o so o
Melo ni mo royin
Mi fe yan lori logo o
Ojo jumo ni mo ma dupe
Emi lo dalola mo wa yin o o
Emi lo gbe bori mo gbe o ga o
Ife re simi ga ju orun ihun aye
Ife re simi ga ju awon oke lo
Mio yin o Olorun ayo
Ife re simi ga ah o fe mi
Eni kan be to fe ran wa
Ah o fe wa
Ife re ju ti ye kan lo
Ah o fe wa
Ore aye
Ore aye kan wa sile
B' oni dun ola le koro
Sugbon Ore yi ko ntan ni
A! O fe wa!
Iye ni fun wa b' a ba mo
A! O fe wa!
Ro b' a ti je ni 'gbese to
A! O fe wa!
Eje Re l' O si fir a wa
Nin' aginju l' O wa wa ri
O si mu wa wa s' agbo Re
A! O fe wa!
IFe re simi ga ju orun ihun aye
Ife re simi ga ju awon oke lo
Mio yin o Olorun ayo
Ife re simi ga ah o fe mi
Emi lo dalola mo wa yin o o
Emi lo gbe bori mo gbe o ga o
Ife re simi ga ju orun ihun aye
Ife re simi ga ju awon oke lo
Mio yin o Olorun ayo
Ife re simi ga ah o fe mi