Back to Top

Olamony - Ye Toka (Live) Lyrics



Olamony - Ye Toka (Live) Lyrics
Official




Ọ̀rẹ́ mi I'm only human
We're all about mistakes
Forget about perfection
We all have heavy days
The day looks dark and gloomy
The sun won't show its rays
But days are gonna come
When on me it shines it's face
Èmi ìwọ̀fà
Ìwọ ìwọ̀fà
Oní bàbá ní k'o gb'owó wá
Ṣé o ti san tìrẹ
San tìrẹ
Lọ san tìrẹ ná
Lọ san tìrẹ ná
Yé tọ́ka sí mi
The loud vessels are empty
It's like a sounding trumpet
The sinner has a future
No saint believes they're perfect
The peacock is the proudest
But the eagle soars the highest
And every soul on earth
Like the seas would face a tempest
Èmi ìwọ̀fà
Ìwọ ìwọ̀fà
Oní bàbá ní k'o gb'owó wá
Ṣé o ti san tìrẹ
San tìrẹ
Lọ san tìrẹ ná
Lọ san tìrẹ ná
Yé tọ́ka sí mi
Gbogbo wa la jẹ gbèsè
Kò s'ẹ́ni tó da ju ẹnìkan lọ
A ti rí ọba tí ó d'ẹrú
A ti rí ẹrú tí ó d'ọba
A ti rí ìjòyè tí ó d'ìwọ̀fà
Ọ̀rẹ́ ṣe tìrẹ, jẹ́'n ṣe tèmi
Èmi ìwọ̀fà
Ìwọ ìwọ̀fà
Oní bàbá ní k'o gb'owó wá
Ṣé o ti san tìrẹ
San tìrẹ
Lọ san tìrẹ ná
Lọ san tìrẹ ná
Yé tọ́ka sí mi
San tìrẹ
Lọ san tìrẹ ná
Lọ san tìrẹ ná
Yé tọ́ka sí mi
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


English

Ọ̀rẹ́ mi I'm only human
We're all about mistakes
Forget about perfection
We all have heavy days
The day looks dark and gloomy
The sun won't show its rays
But days are gonna come
When on me it shines it's face
Èmi ìwọ̀fà
Ìwọ ìwọ̀fà
Oní bàbá ní k'o gb'owó wá
Ṣé o ti san tìrẹ
San tìrẹ
Lọ san tìrẹ ná
Lọ san tìrẹ ná
Yé tọ́ka sí mi
The loud vessels are empty
It's like a sounding trumpet
The sinner has a future
No saint believes they're perfect
The peacock is the proudest
But the eagle soars the highest
And every soul on earth
Like the seas would face a tempest
Èmi ìwọ̀fà
Ìwọ ìwọ̀fà
Oní bàbá ní k'o gb'owó wá
Ṣé o ti san tìrẹ
San tìrẹ
Lọ san tìrẹ ná
Lọ san tìrẹ ná
Yé tọ́ka sí mi
Gbogbo wa la jẹ gbèsè
Kò s'ẹ́ni tó da ju ẹnìkan lọ
A ti rí ọba tí ó d'ẹrú
A ti rí ẹrú tí ó d'ọba
A ti rí ìjòyè tí ó d'ìwọ̀fà
Ọ̀rẹ́ ṣe tìrẹ, jẹ́'n ṣe tèmi
Èmi ìwọ̀fà
Ìwọ ìwọ̀fà
Oní bàbá ní k'o gb'owó wá
Ṣé o ti san tìrẹ
San tìrẹ
Lọ san tìrẹ ná
Lọ san tìrẹ ná
Yé tọ́ka sí mi
San tìrẹ
Lọ san tìrẹ ná
Lọ san tìrẹ ná
Yé tọ́ka sí mi
[ Correct these Lyrics ]
Writer: Isreal Akindipe
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid

Back to: Olamony



Olamony - Ye Toka (Live) Video
(Show video at the top of the page)


Performed By: Olamony
Language: English
Length: 4:25
Written by: Isreal Akindipe
[Correct Info]
Tags:
No tags yet