Baba Eledumare
Wa gbebo wa o
Ti won ba nkobi laiye
Ma je ko je ti wa
Oyigiyigi atobito
Wa gb'ebo wa o
Baba Eledumare
Wa gbebo wa o
Ti won ba nkobi laiye
Ma je ko je ti wa
Oyigiyigi atobito
Wa gb'ebo wa o
Oluwa awon oluwa
Olorun to nje emi ni
A ji p'ojo iku da
Wa saanu wa
Oluwa awon oluwa
Olorun to nje emi ni
A ji p'ojo iku da
Wa saanu wa
Saanu aya
Dakun saanu omo
Saanu orile ede yi o
Baba wa gb'ebe wa
Baba Eledumare
Wa f'ogo re han
Gbogbo ekun to ti wo
Wa gbe won ga o
Elerunniyi, a ba n'ise
Wa bukun un wa
Kiniun eya Judah o
Se b'eyin la nke si
Oba to ju gbogbo aiye lo
To tun wa wo sanmo bi aso
Kiniun eya Judah o
Se b'eyin la nke si
Oba to ju gbogbo aiye lo
To tun wa wo sanmo bi aso
Halleluyah ni fun o
A gb'osuba fun o
Ogo nla lo ye o
Baba wa gba'yin wa
Baba Eledumare
Wa fun wa l'ayo
Ekun, ofo, ati ose
Mu won jina siwa
Olurapada ope ye o
Wa so gba wa s'ire
Oba to lo kanrin kese
Olu orun o lowo gbogboro
A bu bu tan awimayehun
Oba to n mu ileri se
Oba to lo kanrin kese
Olu orun o lowo gbogboro
A bu bu tan awimayehun
Oba to n mu ileri se
Ogo ni fun baba
Ogo ni fun omo
Emi mimo afinimona
Baba wa gb'ogo wa
Baba Eledumare
Wa gbe wa s'oke
Gbogbo oju to ti fo
Wa si won n'iye
Olugbala, oba toto
Wa fun wa l'ayo
Baba Eledumare
Wa gbebo wa o
Ti won ba nko bi laiye
Ma je ko je ti wa
Oyigiyigi atobito
Wa gb'ebo wa o
Oyigiyigi atobito
Wa gb'ebo wa o