Back to Top

Olufemi Oluwafemi - Bi Eji Owuro (feat. Olayinka Oluwafemi & Oluwaseun Adenola) Lyrics



Olufemi Oluwafemi - Bi Eji Owuro (feat. Olayinka Oluwafemi & Oluwaseun Adenola) Lyrics
Official




Bi eji owuro
Baba ti ko're wa o
Lati oke
Lati fun wa
Fun wa l'ayo
Bi itana to ntan
Ife re n'to ni s'ona
Lati mu wa
De ebute
Ebute ayo
Bi apata abo
Oluwa ns'iji b'owa
Lati pa mo
Ninu ewu
Ewu aiye
Bi odo nla to nsan
Aanu re wa titi lai
Lati f'oriji
Gbogbo ai se dede wa
Bi irawo to ntan
Ife re si wa sibe
Bo ti wa n'ibere
Beni yio wa lai lai
Bi apata to ga
Abo re duro sansan
Lati da bobo
Awon to r'omo Jesu
Bi ife a lai l'opin
Jesu f'emi re s'ile
Lati gba gbogbo wa
Ninu ewu aiye
Korin Halleluyah
Oluwa si wa sibe
Pa ni mo nnu lala
De wa lade ogo
K'orin Halleluyah
Omo Irapaada
Ke p'oluwa
Yio si fun wa
Fun wa l'ayo
Eyo nnu Oluwa
Eyin omo ogun
E ke Hossaanah
E yin Oba orun
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


English

Bi eji owuro
Baba ti ko're wa o
Lati oke
Lati fun wa
Fun wa l'ayo
Bi itana to ntan
Ife re n'to ni s'ona
Lati mu wa
De ebute
Ebute ayo
Bi apata abo
Oluwa ns'iji b'owa
Lati pa mo
Ninu ewu
Ewu aiye
Bi odo nla to nsan
Aanu re wa titi lai
Lati f'oriji
Gbogbo ai se dede wa
Bi irawo to ntan
Ife re si wa sibe
Bo ti wa n'ibere
Beni yio wa lai lai
Bi apata to ga
Abo re duro sansan
Lati da bobo
Awon to r'omo Jesu
Bi ife a lai l'opin
Jesu f'emi re s'ile
Lati gba gbogbo wa
Ninu ewu aiye
Korin Halleluyah
Oluwa si wa sibe
Pa ni mo nnu lala
De wa lade ogo
K'orin Halleluyah
Omo Irapaada
Ke p'oluwa
Yio si fun wa
Fun wa l'ayo
Eyo nnu Oluwa
Eyin omo ogun
E ke Hossaanah
E yin Oba orun
[ Correct these Lyrics ]
Writer: Benedict Oluwafemi
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid




Olufemi Oluwafemi - Bi Eji Owuro (feat. Olayinka Oluwafemi & Oluwaseun Adenola) Video
(Show video at the top of the page)


Performed By: Olufemi Oluwafemi
Language: English
Length: 4:09
Written by: Benedict Oluwafemi
[Correct Info]
Tags:
No tags yet