Back to Top

Iwa loba Awure Video (MV)




Performed By: Omo Yoruba Ni Wa
Language: Spanish
Length: 2:11
Written by: Yisel Pèrez Betancort, Kilian Ruano Afonso
[Correct Info]



Omo Yoruba Ni Wa - Iwa loba Awure Lyrics




Ìwà loba Àwúre ìwà o

Ìwà ìwà
Ìwà ìwà
Iwa lọba Àwúre
Ìwà o
Ìwà loba Àwúre ìwà o
Ìwà lọba Àwúre
Ìwà o

Ẹni ba níwà tutu u
Ohun gbogbo lónìí
Ìwà loba Àwúre ìwà o
Ẹ jẹ́ ká nìwà tutu
Ká lè ráyè gbé
Ká ní sùúrù
Ká ní teríbà

Ìwà a

Ìwà loba Àwúre, ìwà o

Ìwà a

Ìbàjé ọmọnìkejì
Kò dára rárá
Kìí gbọ́ kìí gbá ọ
Ko ṣeré níbẹ̀ o

Ìwà ìwà
Ìwà ìwà
Iwa lọba Àwúre
Ìwà o
Ìwà loba Àwúre ìwà o
Ìwà lọba Àwúre
Ìwà o

Ẹni ba níwà tutu u
Ohun gbogbo lónìí
Ìwà loba Àwúre ìwà o
Ẹ jẹ́ ká nìwà tutu
Ká lè ráyè gbé
Ká ní sùúrù
Ká ní teríbà

Ìwà a
Ìwà loba Àwúre, ìwà o
Ìwà a
Ìwà loba Àwúre, ìwà o
Ìwà a

Ìbàjé ọmọnìkejì
Kò dára rárá
Kìí gbọ́ kìí gbá ọ
Ko ṣeré níbẹ̀

Ìwà a
Ìwà loba Àwúre, ìwà o
Ìwà a
Ìwà loba Àwúre, ìwà o

Ìwà aa
Ìwà loba Àwúre, ìwà o
Ìwà aa
Ìwà loba Àwúre, ìwà o
Ìwà aa

Ìwà a (a-a-a)
Ìwà loba Àwúre, ìwà o
Ìwà a a (a-a-a)
Ìwà loba Àwúre, ìwà o
Ìwà a a (a-a-a)
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


Spanish

Ìwà loba Àwúre ìwà o

Ìwà ìwà
Ìwà ìwà
Iwa lọba Àwúre
Ìwà o
Ìwà loba Àwúre ìwà o
Ìwà lọba Àwúre
Ìwà o

Ẹni ba níwà tutu u
Ohun gbogbo lónìí
Ìwà loba Àwúre ìwà o
Ẹ jẹ́ ká nìwà tutu
Ká lè ráyè gbé
Ká ní sùúrù
Ká ní teríbà

Ìwà a

Ìwà loba Àwúre, ìwà o

Ìwà a

Ìbàjé ọmọnìkejì
Kò dára rárá
Kìí gbọ́ kìí gbá ọ
Ko ṣeré níbẹ̀ o

Ìwà ìwà
Ìwà ìwà
Iwa lọba Àwúre
Ìwà o
Ìwà loba Àwúre ìwà o
Ìwà lọba Àwúre
Ìwà o

Ẹni ba níwà tutu u
Ohun gbogbo lónìí
Ìwà loba Àwúre ìwà o
Ẹ jẹ́ ká nìwà tutu
Ká lè ráyè gbé
Ká ní sùúrù
Ká ní teríbà

Ìwà a
Ìwà loba Àwúre, ìwà o
Ìwà a
Ìwà loba Àwúre, ìwà o
Ìwà a

Ìbàjé ọmọnìkejì
Kò dára rárá
Kìí gbọ́ kìí gbá ọ
Ko ṣeré níbẹ̀

Ìwà a
Ìwà loba Àwúre, ìwà o
Ìwà a
Ìwà loba Àwúre, ìwà o

Ìwà aa
Ìwà loba Àwúre, ìwà o
Ìwà aa
Ìwà loba Àwúre, ìwà o
Ìwà aa

Ìwà a (a-a-a)
Ìwà loba Àwúre, ìwà o
Ìwà a a (a-a-a)
Ìwà loba Àwúre, ìwà o
Ìwà a a (a-a-a)
[ Correct these Lyrics ]
Writer: Yisel Pèrez Betancort, Kilian Ruano Afonso
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid


Tags:
No tags yet