Sali kuli la faya mi laki lo fayato
Moseri monda fun oba mi atófaratì
Ojókòó ló òókán, ò ńwo bí ayé se rí
Ó ti sú e bí ohun gbogbo se rí
Ìdàmú òhun wàhálà ló gba okàn re so
Odélé oní ifá, wán ní ko wá gbé ebo
Odélé olósanyè, bákonóò lórí
Ô la jú ríran , koróba tótó o
Ô ní ìmò òye pé oba òkè tó o
Pé bó se ńse ìlérí , ló se ń mu se
Bó se ńse ìlérí, ló se ń mu se
Kò jé yę májémú rárá oh oh
Kò jé yę májémú rárá oh oh
Sumiala, kaya mi
Sokaya mi, kala mi
Baba mi oba Tótó
Over the moon, over the sea
There's nobody like you
When I am down, you cover me
Alone nobody like you
Olórun oba mi dákun wa gbàmí
Májè káyá kó rí ìdí mi
Òyòyò tí nyomo lófìn ò Jésù
Ebí olórun ńse bebe bíì tàtijó
Àwa ni kí á máa sin bàbá bi tàtijó
Pé bó se ńse ìlérí , ló se ń mu se
Bó se ńse ìlérí, ló se ń mu se
Kò jé yę májémú rárá oh oh
Kò jé yę májémú rárá oh oh
You cover me baba
Wetin you to sweet me
Ó dùn mó mi nínú
Ó gbé mi dé bè tán
Atóbájayé
Gbongbon ìdílé Jésè e sé