Sekun mi derin
Kia kia
Sekun mi derin oo
Ato obi ju oo
Ibi oro mi ayori si oo
Je o je'bi re
Sekun mi derin
Kia kia
Sekun mi derin oo
Ato obi ju oo
Ibi oro mi ayori si oo
Je o je'bi re
Oluwa iwo da aaa
Emi ma nwoju re ee
Si'leku aanu sile
Ma je ke mi lo lofo
Sekun mi derin
Kia kia
Sekun mi derin oo
Ato obi ju oo
Ibi oro mi ayori si oo
Je o je'bi re
Mo n bere eeee
Mo n kan 'lekun ooo
Mo n bere eeee
Mo n kan' lekun ooo
L'oruko Oluwa
Orun n mi si ooooo
Sekun mi derin
Kia kia
Sekun mi derin oo
Ato obi ju oo
Ibi oro mi ayori si oo
Je o je'bi re