Ancient of days
Olorun 1930
Aye r'ope otiku
Olorun 1930 aye r'ope oti lo ni
Agbara igba ni oun be k'oyipada
Dide k'owa sebi akoni
Olorun 1930 Olorun Babalola
Olorun 1930 olorun a'tobiju
O'n mu aro l'arada
O'n ji oku dide
O'n s'agan d'olomo
O'n m'aboyun bi were
Olorun aposteli eseee
K'ilolese ipa n be l'owo re
Agbara n be l'owo re
Oke ga j'oke
Olorun 1930 aye r'ope oti lo ni
Agbara igba ni oun be k'oyipada
Dide k'owa sebi akoni
Olotito o l'olorun mi o
Olotito o l'olorun mi
Oba ti ki s'egbe
Oba ti ki s'eke
T'oba sa ti s'oro dandan oro re a se
Olotito o l'olorun mi
Eniyan l'ap'adegun
Won atun pe k'ogun mo
Be'ni yan soro k'oma nimu se
Sugbon olorun t'emi k'oma ki n yi pada rara
Olorun 1930 aye r'ope oti lo ni
Agbara igba ni oun be k'oyipada
Dide k'owa sebi akoni
Faraoh wipe tani oluwa t'oran mose ni'se
Sennacherubu wipe t'ani olorun ti Hezekiah oba gboju le
Nebuchadnezzar o gberaga l'aya re o sata olorun awon heberu meta
Gbogbo won pata l'opare
Oju siti awon agberaga
Jehovah l'oke dakun baba
Jek'oju koti gbogbo awon ota mi
Olorun 1930 aye r'ope oti lo ni
Agbara igba ni oun be k'oyipada
Dide k'owa sebi akoni
Alagbara l'oluwa Ologun l'oluwa
Oba t'onja f'awon omo re gbogbo agbara je tire
Olorun 1930
Aye r'ope otiku
Olorun 1930 aye r'ope oti lo ni
Agbara igba ni oun be k'oyipada
Dide k'owa sebi akoni
Agbara olorun mi po
O un l'olana l'ori omi papa n jo o
Igbe o derun
Omo olorun l'ana fun mi
Olorun 1930 aye r'ope oti lo ni
Agbara igba ni oun be k'oyipada
Dide k'owa sebi akoni 2x
Alagbara l'olorun mi olorunmi t'oga resp