WHEN THERE IS LIGHT BY SEMILOGO
Jeki malekoto Kotan sinu ayemi
Jeki imole kotan Kotan soju ona mi
GBati imole batan Ireti nbe
GBati reti bawa Imuse ileri ade
Jeki imole kotan Kotan sinu aye mi
Jeki imole kotan Kotan soju ona mi
Ii atetekise Ti aye wani juju
Osiso fo okunkun wa loju ibu
Olorun pase wipe ki imole kotan
Afigbati imole tan ni Ireti ayetode
Imole ni O O iwoni imole ooo
Eyi ti oba se koseni to keep yi
Afigbati oba de leda ke je nkan
Ile iti o bade won o male gbagbe re
Odede tio bawo wani imo larare
Aye ti oba desi won o male gbagbe re
Tete desaye mi kin le ni Ireti ooo
Jeki imole kotan Kotan sinu ayemi
Jeki imole kotan Kotan soju ona mi
Gbati imole batan Ireti nbe
GBati reti bawa Imuse Ileri Ade
Jeki imole kotan Kotan sinu aye mi
Jeki imole kotan Kotan soju ona mi
Imole oo Tete desaye mi baba
Imole oo Tete desaye mi
Imole oo Tete desaye mi olua
Imole oo Tete desaye mi
Because when there is light there is hope
Imole oo Tete desaye mi
When there is light there will be direction
Imole oo Tete desaye mi
When there is light there will be solution
Imole oo Tete desaye mi
Imole oo Tete desaye mi baba
I male oho Tete de saye mi
When there is light no more sorrow
Imole oo Tete desaye mi