Back to Top

SeyePaul Music - E jù béèlo (God Beyond Description) Lyrics



SeyePaul Music - E jù béèlo (God Beyond Description) Lyrics




Kiki ogo, kiki ogo, kiki ola
Kiki ogo, kiki ogo kiki Agbara
Kiki ogo, kiki ogo, kiki ola
Ofi m'ole s'a so bora o Olorun kiki ogo
Kiki ogo, kiki ogo, kiki ola
Kiki ogo, kiki ogo kiki Agbara
Kiki ogo, kiki ogo, kiki ola
Ofi m'ole s'a so bora o Olorun kiki ogo

Oloju kan to nw'egbegberu eniyan
Oba t'o nbo gbogbo eniyan nile aye
Talo tobi to O
Talo ju O lo o
Aditu ijinle ajade mama tan nle
E de po ju bee lo o
E ju bee lo Baba
Ki ni mo fe Fi s'aka we Re, Oba t'otobi
E ju bee lo o

E ju bee lo o
E ju bee lo Baba
Ki ni mo fe Fi s'aka we Re
Oba t'otobi
E ju bee lo o

Oku ojo kerin, O ji dide
Iwo lo nsewosan ti o ni gbowo
Iwo lo nso loriburuku d'olori ire
Taatie le bi le'jo rara
Aso're kani laya Iwo nikan loba
Ogbeni nija keru o b'onija
Oran'mo lajo, wo'le d'omo ti o yipo pada
E po ju b'aye se lero pee je

E ju bee lo o
E ju bee lo Baba
Ki ni mo fe Fi s'aka we Re
Oba t'otobi
E ju bee lo o

Eeyan ti o mo'nu ro
Ni o ni le dupe lowo Olu
Moti gbo'pee mi de o,
Olorun mi bi mo se ma nse
Gb'ope e mio baba rere

E ju bee lo o
E ju bee lo Baba
Ki ni mo fe Fi s'aka we Re
Oba t'otobi
E ju bee lo o
E ju bee lo o
E ju bee lo Baba
Ki ni mo fe Fi s'aka we Re
Oba t'otobi
E ju bee lo o

Mo wo aye yi o at'Orun
Mo ri pe ko s'alagbara mo
Alagbara le wa l'oni o
W'an deni ile b'odola
Iwo lo ma wa titi laelae

E ju bee lo o
E ju bee lo Baba
Ki ni mo fe Fi s'aka we Re
Oba t'otobi
E ju bee lo o
E ju bee lo o
E ju bee lo Baba
Ki ni mo fe Fi s'aka we Re
Oba t'otobi
E ju bee lo o

Olorun t'o ntan m'ole saye
Olorun ti k'Olafiwe
Olorun ti kosenikeni t'o mo bere Re
T'ao le r'opin re laelae

E ju bee lo o
E ju bee lo o
E ju bee lo o
E ju bee lo o
E ju bee lo o
E ju bee lo o
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.




Kiki ogo, kiki ogo, kiki ola
Kiki ogo, kiki ogo kiki Agbara
Kiki ogo, kiki ogo, kiki ola
Ofi m'ole s'a so bora o Olorun kiki ogo
Kiki ogo, kiki ogo, kiki ola
Kiki ogo, kiki ogo kiki Agbara
Kiki ogo, kiki ogo, kiki ola
Ofi m'ole s'a so bora o Olorun kiki ogo

Oloju kan to nw'egbegberu eniyan
Oba t'o nbo gbogbo eniyan nile aye
Talo tobi to O
Talo ju O lo o
Aditu ijinle ajade mama tan nle
E de po ju bee lo o
E ju bee lo Baba
Ki ni mo fe Fi s'aka we Re, Oba t'otobi
E ju bee lo o

E ju bee lo o
E ju bee lo Baba
Ki ni mo fe Fi s'aka we Re
Oba t'otobi
E ju bee lo o

Oku ojo kerin, O ji dide
Iwo lo nsewosan ti o ni gbowo
Iwo lo nso loriburuku d'olori ire
Taatie le bi le'jo rara
Aso're kani laya Iwo nikan loba
Ogbeni nija keru o b'onija
Oran'mo lajo, wo'le d'omo ti o yipo pada
E po ju b'aye se lero pee je

E ju bee lo o
E ju bee lo Baba
Ki ni mo fe Fi s'aka we Re
Oba t'otobi
E ju bee lo o

Eeyan ti o mo'nu ro
Ni o ni le dupe lowo Olu
Moti gbo'pee mi de o,
Olorun mi bi mo se ma nse
Gb'ope e mio baba rere

E ju bee lo o
E ju bee lo Baba
Ki ni mo fe Fi s'aka we Re
Oba t'otobi
E ju bee lo o
E ju bee lo o
E ju bee lo Baba
Ki ni mo fe Fi s'aka we Re
Oba t'otobi
E ju bee lo o

Mo wo aye yi o at'Orun
Mo ri pe ko s'alagbara mo
Alagbara le wa l'oni o
W'an deni ile b'odola
Iwo lo ma wa titi laelae

E ju bee lo o
E ju bee lo Baba
Ki ni mo fe Fi s'aka we Re
Oba t'otobi
E ju bee lo o
E ju bee lo o
E ju bee lo Baba
Ki ni mo fe Fi s'aka we Re
Oba t'otobi
E ju bee lo o

Olorun t'o ntan m'ole saye
Olorun ti k'Olafiwe
Olorun ti kosenikeni t'o mo bere Re
T'ao le r'opin re laelae

E ju bee lo o
E ju bee lo o
E ju bee lo o
E ju bee lo o
E ju bee lo o
E ju bee lo o
[ Correct these Lyrics ]
Writer: Oluwaseye Adeleke
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid




SeyePaul Music - E jù béèlo (God Beyond Description) Video
(Show video at the top of the page)

Tags:
No tags yet