Hmmmmm
Ehhh ehhh ehhh
There is no one like you Jehovah
We worship you, we worship you
Oba aseyi o wun oba ni
Oba aseyi o wun oba ni
Oba to le ji to le paa oo
Oba aseyi o wun oba ni
E ma ma bii lere oba ni
E ma ma bii lere oba ni
Oba to n'ole to n'oke to no'bi gbo
Kabiyesi o o olola nla
To ba njagun a dabi e ni ti o le gbani ye
To ba ngbaani, a dabi eni ti o le jagun
Oun l'olorun ti ko yipo pada
Kabiyesi o o, olori aiye
Iwo shaaaa l'olorun o o o
Atobajaiye baba 'dumare ee
Mo sunmo'ba ni won egbeje
Mo jina so'ba niwon egbefa
Mo teriba o o o o
Ewa ri, Ewa ri, Ewa ri f'oba ajuni lo
Oba aseyi o wun o oba ni
Oba aseyi o wun oba ni
Oba to le paa to le jii oo
Oba aseyi o wun oba ni
Awon science aiye yi gbiyonju titi titi titi
Won wa olorun kiri won wa de'nu osupa o
Won wa de'nu òrùn, won wa de'nu aféfé
Won o ri iru re won wa so pe koosi
Wo ni e ma si o, kosi iru olorun tiwa
Ta la ba fi o we, laiye lorun kosi o
Ade ori re taloba o se, irukere oye ti o mu dani talo se
Kosi e e, koma si eni to le moo o
Aditu, Ajulo, Ajutan, Arugbo ojo, Jojolo
Baba mi orogojigo, oloruko nla oo o o o
Iwo shaa l'olorun baba agba
Kabiyesi ooo, olori aiye
Orun o gba, o f'aiye se 'bugbe
Aiye o gba o, o f'orun se 'bugbe
Mi o riru e ri, l'aiye l'orun, l'aiye l'orun, l'aiye l'orun kosi
Kabiyesi oooo iwo shaaaa
Oba aseyi o wun o oba ni
Oba aseyi o wun oba ni
Oba to le paa to le jii oo
Oba aseyi o wun oba ni
K'awá so pé
Oba to ni wakati ti mo wa
Oo je k'aiye yeeye mi o ma seun
Oba to ni wakati ti mo wa
Oo je k'aiye yeeye mi o ma seun
Oba to ni wakati ti mo wa
Oo je k'aiye se shior mi o ma seun
Oba to ni wakati ti mo wa
Oo je k'aiye yeeye mi o ma seun