Ó ti yà ó wọn kọrin lọ sí waju Ogun
Ó ti yà ó, àwọn ìyàwó ń kígbe wọn ké o
Ọmọ yín kò?
Ìyàwó yín kò?
Wọn gbàgbé gbógbo tí tí won
Ógùn lápá osi, ogún lápá otun o
Odode Iwaju ogun
Odode Iwaju ogun
Sójà, Ẹrú ó bá ẹ o
Sójà, ṣe ikú ó kà ẹ lara
Sójà, ṣe ó má padà wá lè o?
Sójà, sójà!
Ó tiya o
Jagun jagun kọrin ìjà lo
Ó tiya o
Àkókò idabobo tí de o
Ọmọ yín kò?
Ìyàwó yín kò?
Wọn gbàgbé gbógbo tí tí won
Óju bí ina, ìbon Sango!
Odode Iwaju ogun
Oya ká lọ, ẹ!
Oya ká lọ taje sílè.
Sójà, Ẹrú ó bá ẹ o
Sójà, ṣe ikú ó kà ẹ lara
Sójà, ṣe ó má padà wá lè o?
Sójà, sójà!