Aje
Tete wami oh aje
Wa f'ile mi se ibugbe
Wa se orimi lori olowo bi Davido, k'emi Mayokun
Okiki mi ko kan bi omi OKuN
Lojojumo bi mo se n sise
Mode ma n gbadura
Baba shiju anu womo re
Kin le ma ri anu gba
Oluwa gbemi dide
Elevate me comot for this level way i dey
Baba loke show me the way
Ki ilekun si, baba ma gbagbe mi
K'ona mi la, k'ire wole mi
Iseda mi ko ja fun mi
K'ola wole mi
Aje olokun ani ko ya ilemi
Aje
Tete wami oh aje
Wa f'ile mi se ibugbe
Wa se orimi lori olowo bi Davido, k'emi Mayokun
Okiki mi ko kan bi omi OKuN
Sebi ati je ati mu lo n fa inira, lo n fa arinfin
Ipokipo toh ba wa laye, ile aye yi oo lo titi
Igba melo lama lo laye, ile aye yi o gbagidi
Igba melo lafin gbagbe oshi
Eledumare wire my aza
Shakiti mi ko gbera (omo ope ko gbera)
Eni ti o lowo sebi ohun lo ma n karan
Teru bamo inu ro amo ope da
Ko n sebi kama ni ilara
Tori momo bimose wa seyin, now ewo bi mo se n gara
Aje
Tete wami oh aje
Wa f'ile mi se ibugbe
Wa se orimi lori olowo bi Davido, k'emi Mayokun
Okiki mi ko kan bi omi OKuN
#stanleytunessaveme