Back to Top

Temitope Fash - SÌNMÍKÁR'ELÉ Lyrics



Temitope Fash - SÌNMÍKÁR'ELÉ Lyrics




Sinmikarele
Ololufe Sinmi ka lo o
Sinmikarele
Ile n şu o ooo
Sinmikarele
Ololufe Sinmi ka lo o
Igba ara la n bu ra

Sinmikarele
Ololufe Sinmi ka lo o
Sinmikarele
Ile n şu o ooo
Sinmikarele
Ololufe Sinmi ka lo o
Igba ara la n bu ra

Ololufe mi owon
Amolewa alewa niwa
Oloju arede arewa mi dot com
Dakun Sinmikarele
Je n mu e lo mo awon obi mi
Kalo k'omo lubo
Je n pe o l'anike
Nitori eni ani ta n ke ni o
Je ki n pe o l'ajoke nitori
Eni a n pe Jo oo ke ni o
Jeki n pe o l'akanke nitori
Eni a f'oju kan bi eni f'oju kan
Eso to rewa ti o şe mojukuro ni o
Arewa
Dakun Sinmikarele
Ololufe mi telemi kalo k'omolubo 3x Sinmikarele ah ah
Mase bayi now Oya gangan
Bami gbe s'oke jor

Sinmikarele
Ololufe Sinmi ka lo o
Sinmikarele
Ile n şu o ooo
Sinmikarele
Ololufe Sinmi ka lo o
Igba ara la n bu ra

Sinmikarele
Ololufe Sinmi ka lo o
Sinmikarele
Ile n şu o ooo
Sinmikarele
Ololufe Sinmi ka lo o
Igba ara la n bu ra
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


English

Sinmikarele
Ololufe Sinmi ka lo o
Sinmikarele
Ile n şu o ooo
Sinmikarele
Ololufe Sinmi ka lo o
Igba ara la n bu ra

Sinmikarele
Ololufe Sinmi ka lo o
Sinmikarele
Ile n şu o ooo
Sinmikarele
Ololufe Sinmi ka lo o
Igba ara la n bu ra

Ololufe mi owon
Amolewa alewa niwa
Oloju arede arewa mi dot com
Dakun Sinmikarele
Je n mu e lo mo awon obi mi
Kalo k'omo lubo
Je n pe o l'anike
Nitori eni ani ta n ke ni o
Je ki n pe o l'ajoke nitori
Eni a n pe Jo oo ke ni o
Jeki n pe o l'akanke nitori
Eni a f'oju kan bi eni f'oju kan
Eso to rewa ti o şe mojukuro ni o
Arewa
Dakun Sinmikarele
Ololufe mi telemi kalo k'omolubo 3x Sinmikarele ah ah
Mase bayi now Oya gangan
Bami gbe s'oke jor

Sinmikarele
Ololufe Sinmi ka lo o
Sinmikarele
Ile n şu o ooo
Sinmikarele
Ololufe Sinmi ka lo o
Igba ara la n bu ra

Sinmikarele
Ololufe Sinmi ka lo o
Sinmikarele
Ile n şu o ooo
Sinmikarele
Ololufe Sinmi ka lo o
Igba ara la n bu ra
[ Correct these Lyrics ]
Writer: Temitope Fasesin
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid

Back to: Temitope Fash



Temitope Fash - SÌNMÍKÁR'ELÉ Video
(Show video at the top of the page)


Performed By: Temitope Fash
Language: English
Length: 4:39
Written by: Temitope Fasesin
[Correct Info]
Tags:
No tags yet