Back to Top

TEMPO TEMPO - ESE ODO Lyrics



TEMPO TEMPO - ESE ODO Lyrics




Ìpè tó dún bá wa lójijì.
Eni tó bá ló lè ròhin rè.
Tony Allen ti sípò padà.
Sùgbón títí láé nìrántíì re yóó wà.
(It was a sudden call. A painful narration to share. Tony Allen's transition shall forever
Be remembered).
Smile on you are celebrated.
Shine on, shine on you are a star.
Smile on you are celebrated.
Smile on, smile on you've done us proud.

O Ò ódigbéré o, ódàrìnnàkò.
Ó dojú àlá o - erínwó.
O dewúrée jeléjelé.
O dàgùtàn-an jemòjemò.
O daláàmú tíí je légbèé ògiri.
O dàgbàrá òjò - oò yalémó.
Ìpàdé desè odò - ó dòhún oo.
(You've transcended to the spirit land with the ancestors. We shall meet no more until
Eternity).
Smile on you are celebrated.
Shine on, shine on you are a star.

Ká tóó rérin - ó digbó.
Ká tóó réfòn - ó dòdàn o.
(You are one in a million, a rare gem indeed).

Héè Diípò gbáyé o - ó seeni ire.
Tony Allen ó dòrun-un 're.
O gbá'yé o - o hùwàa're.
Tony Allen ó dòrun-un 're.
Háà ó dòhún o - ó desè odò.
Tony Allen ó dòrun-un 're.

Ìpéjopò ìdùnnú lafi rántíì re.
Tony Allen ó dòrun-un 're.
Aya, omo àtomoo'mo wón gbèyìn-ìn re.
Tony Allen ó dòrun-un 're.
Isé tóo se sílè kòlè bàjé láé.
Tony Allen ó dòrun-un 're.
Ebí, ará , òré o wón sèdáròò 're.
Tony Allen ó dòrun-un 're.
Àjoyò dídùn ni lafi sè 'dáròò re.
Tony Allen ó dòrun-un 're.
(You were a man of depute and dignity.
You leaved a noble and honored life.
The gathering of the family, friends, loved ones and fans remembered and celebrated
You greatly.
Adieu !!! Until we meet at the bank of the river).
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


English

Ìpè tó dún bá wa lójijì.
Eni tó bá ló lè ròhin rè.
Tony Allen ti sípò padà.
Sùgbón títí láé nìrántíì re yóó wà.
(It was a sudden call. A painful narration to share. Tony Allen's transition shall forever
Be remembered).
Smile on you are celebrated.
Shine on, shine on you are a star.
Smile on you are celebrated.
Smile on, smile on you've done us proud.

O Ò ódigbéré o, ódàrìnnàkò.
Ó dojú àlá o - erínwó.
O dewúrée jeléjelé.
O dàgùtàn-an jemòjemò.
O daláàmú tíí je légbèé ògiri.
O dàgbàrá òjò - oò yalémó.
Ìpàdé desè odò - ó dòhún oo.
(You've transcended to the spirit land with the ancestors. We shall meet no more until
Eternity).
Smile on you are celebrated.
Shine on, shine on you are a star.

Ká tóó rérin - ó digbó.
Ká tóó réfòn - ó dòdàn o.
(You are one in a million, a rare gem indeed).

Héè Diípò gbáyé o - ó seeni ire.
Tony Allen ó dòrun-un 're.
O gbá'yé o - o hùwàa're.
Tony Allen ó dòrun-un 're.
Háà ó dòhún o - ó desè odò.
Tony Allen ó dòrun-un 're.

Ìpéjopò ìdùnnú lafi rántíì re.
Tony Allen ó dòrun-un 're.
Aya, omo àtomoo'mo wón gbèyìn-ìn re.
Tony Allen ó dòrun-un 're.
Isé tóo se sílè kòlè bàjé láé.
Tony Allen ó dòrun-un 're.
Ebí, ará , òré o wón sèdáròò 're.
Tony Allen ó dòrun-un 're.
Àjoyò dídùn ni lafi sè 'dáròò re.
Tony Allen ó dòrun-un 're.
(You were a man of depute and dignity.
You leaved a noble and honored life.
The gathering of the family, friends, loved ones and fans remembered and celebrated
You greatly.
Adieu !!! Until we meet at the bank of the river).
[ Correct these Lyrics ]
Writer: Francois xavier BOSSARD, Motunrayo OROBIYI, Nicolas GIRAUD
Copyright: Lyrics © LA FAMILIA DE FRANCIA

Back to: TEMPO TEMPO



TEMPO TEMPO - ESE ODO Video
(Show video at the top of the page)

Tags:
No tags yet