Back to Top

Tolu Akande - Ma Toju Mi Lyrics



Tolu Akande - Ma Toju Mi Lyrics
Official




Bi mo ti ri: laisawawi
Sugbọn nitori ẹjẹ Rẹ
B'O si ti pe mi pe ki n wa
Olugbala, mo de, mo de
Bi mo ti ri: 'Wọ o gba mi
'Wọ o gba mi tọwọ-tẹsẹ
'Tori mo gba 'leri Rẹ gbọ
Olugbala, mo de, mo de
MA tọju mi Jehofa nla
Ero l'ayé osi yi
Emi ko n'okun, Iwọ ni
F' ọw' agbara di mi mu
Ounjẹ ọrun, Ounjẹ ọrun
Ma bọ mi titi lailai
Silẹkun isun ogo ni
Orisun imarale
Jẹ ki imọlẹ Rẹ ọrun
Se amọna mi jalẹ
Olugbala, Olugbala
S'agbara at' asa mi
'Gba mo ba tẹ ẹba Jọrdan
F'ọkan ẹru mi balẹ
Iwọ t'o ti sẹgun iku
Mu mi gunlẹ Kenaan jẹ;
Orin iyin, Orin iyin
L'emi o fun Ọ titi
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


English

Bi mo ti ri: laisawawi
Sugbọn nitori ẹjẹ Rẹ
B'O si ti pe mi pe ki n wa
Olugbala, mo de, mo de
Bi mo ti ri: 'Wọ o gba mi
'Wọ o gba mi tọwọ-tẹsẹ
'Tori mo gba 'leri Rẹ gbọ
Olugbala, mo de, mo de
MA tọju mi Jehofa nla
Ero l'ayé osi yi
Emi ko n'okun, Iwọ ni
F' ọw' agbara di mi mu
Ounjẹ ọrun, Ounjẹ ọrun
Ma bọ mi titi lailai
Silẹkun isun ogo ni
Orisun imarale
Jẹ ki imọlẹ Rẹ ọrun
Se amọna mi jalẹ
Olugbala, Olugbala
S'agbara at' asa mi
'Gba mo ba tẹ ẹba Jọrdan
F'ọkan ẹru mi balẹ
Iwọ t'o ti sẹgun iku
Mu mi gunlẹ Kenaan jẹ;
Orin iyin, Orin iyin
L'emi o fun Ọ titi
[ Correct these Lyrics ]
Writer: Tolu Akande
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid

Back to: Tolu Akande



Tolu Akande - Ma Toju Mi Video
(Show video at the top of the page)


Performed By: Tolu Akande
Language: English
Length: 5:08
Written by: Tolu Akande
[Correct Info]
Tags:
No tags yet