Assalaamu 'Alaikum
Wa Rahmatullahi Wa Barakatuh
Nle oo, Baba mi, Iya mi
Oko mi, Nle ooo
Gbogbo e no lon se po
Olohun awa pelu e ooo
Abdulmojeed Oluwanishola Babatunde
Omo comfort
Olohun a se anu re, awa pelu e
Aku Odun, Aku I yedun
Adura e agba
Ayo e Akun
Li lo bi bo e a maja sope
Ada wole
Afokan te, Olohun oni je ko pada di ibanuje
Wa se aseyori ninu Odun yi Olohun
Ilekun Anu ti Olohun si, olohun o ni ti
Alekun e asi fun e
Gbo gbo Ibi to se anu e de Olohun o nije ko taku
Olohun oma nije otaku
Alekun sise Olohun a ba mi se fun e
Jije mumu aje, ama, a aje irorun
Lilo bibo e aja si ope
Oni, Owo e oni kan isale apo
Gbogbo igba to ban lo to ban bo
Oni jo eni tan wa ni ti buruku
Kadara aburu oni ko le e Lori