Back to Top

Tunmbi Obasa - O'mbo Lyrics

Tunmbi Obasa - O'mbo Lyrics

O'Mbo, e ma se j'afara
Jesu mi nbo, lati ko wa lo s'oke lo s'ile
O'Mbo, ara, e mura sile
Olurapada, Alagbawi mi nbo

O'Mbo, e ma se j'afara
Jesu mi nbo, lati ko wa lo s'oke lo s'ile
O'Mbo, ara, e mura sile
Olurapada, Alagbawi mi nbo

O ti se'leri, O le mi nlo, n o pada bo
Lati wa ko ayanfe lo s'ibi itura

O ti se'leri, O le mi nlo, n o pada bo
Lati wa ko ayanfe lo s'ibi itura

Ileri Ayo to se fun mi, ni n o di mu o
Ogun Aiye ko ni gba l'owo mi sonu mo duro
Di mi mu Baba, ma je ki n pada seyin
Je ki n ba Jesu mi j'Oba n'ikehin
O'Mbo se

O'Mbo, e ma se j'afara
Jesu mi nbo, lati ko wa lo s'oke lo s'ile
O'Mbo, ara, e mura sile
Olurapada, Alagbawi mi nbo!

O'Mbo, e ma se j'afara
Jesu mi nbo, lati ko wa lo s'oke lo s'ile
O'Mbo, ara, e mura sile
Olurapada, Alagbawi mi nbo

Oun aimo, ko ni wo'le ologo
Eru ese, to n de o mo le, ja so nu

Oun aimo, ko ni wo'le ologo
Eru ese, to n de o mo le, ja so nu

Iwe mimo so fun yin pe ke je mimo o
Bi Baba yin, Orun se je mimo o ara
Emi Mimo Olorun ma se fi mi sile e
K'emi ko le d'Ade Ogo n ikehin

Ipe yio dun
Jesu yio yo l'oke
Ipe yio dun
Jesu yio yo l'oke
Awon oku, ninu Jesu yio ji dide
Awon ayanfe, yi o si wa tele won
Lo pade Oludande l'awo sanmo

Ipo k'ipo ti mo ba wa
Boya kiku tabi yiye
Jesu Oluwa, je ki n j'Oba
Pelu Re n'ikehin
Onigbagbo e d'amure
Alaigbagbo e gba Jesu
Omo Olorun nbo wa j'Oba
B'aiye fe bo ko

Jesu mi n bo, Om'Olorun nbo
Jesu mi n bo, O'Mbo O'Mbo O'Mbo egbo
Jesu mi n bo, O'Mbo, O'Mbo, O'Mbo

[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.

Writer: Tunmbi Obasa
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid

Back to: Tunmbi Obasa

Tunmbi Obasa - O'mbo Video
(Show video at the top of the page)

Performed By: Tunmbi Obasa
Language: English
Length: 7:45
Written by: Tunmbi Obasa

Tags:
No tags yet