Èlédùmarè jẹ́ kí n gbé temí soke
Uhm uhm uhm
Uhm uhm uhm uhm
Ayomide tí lè bá tí mo
Ógo ẹ má má buyo ní
Nínú orin tó ń kọ yìí
Orí ẹ a kó ọkè
Àṣẹ Yorí ló má ṣe
Story of life
Story of life
Baba Change to success
Every body gat a story
Every body gat a story
Story before success
Story before success
Story of life
Story of life
Baba Change to success
Every body gat a story
Every body gat a story
Story before success
Story before success
Listen
I do it for the hustle
I do it for the fame
So many ish but man keep on chase
No no I no fit give up na me get the blame
At the end of the day slow but steady wins the race
I know where I come from
But I no know where I dey go ooo
So many songs
Baba God which one go blow
We don face many yawa cause we wan perform for show
Yeah
Don't gain the world and lose your soul
Wisdom is better than silver or Gold Gold Gold
T jones on the mix
Eh
Lágbára Ọlọrun báyìí
Ọlọrun má dúró tí ẹ ní
Ó ní dáàmú
Ógo má má tán kákírí fún rere ní
Òkíkí ẹ mámá tán fún rere ní
Gbogbo Agbáyé báyìí
Tó ń bá tí gbọ́ orin ẹ báyìí
Agbọ̀ dùn lómá má gbọ́
Lágbára Ọlọrun báyìí
Ómá má lọ́ sóké ní
Ó ní rìn lẹ́
Bó ṣe má jẹ́ ní yẹn
Lágbára Ọlọrun
Èlédùmarè jẹ́ kí n gbé temí soke
Uhm uhm uhm
Uhm uhm uhm uhm
Written by Osinowo Ayomide Joshua